Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Galatia 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọn ń fẹ́ kí àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn mọ̀ wọ́n ní ẹni rere ni wọ́n fẹ́ fi ipá mu yín kọlà, kí àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn má baà ṣe inúnibíni sí wọn nítorí agbelebu Kristi.

Ka pipe ipin Galatia 6

Wo Galatia 6:12 ni o tọ