Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Galatia 3:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ òfin wá lòdì sí àwọn ìlérí Ọlọrun ni bí? Rárá o! Bí ó bá jẹ́ pé òfin tí a fi fúnni lè sọ eniyan di alààyè, eniyan ìbá lè di olódodo nípa òfin.

Ka pipe ipin Galatia 3

Wo Galatia 3:21 ni o tọ