Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Galatia 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, ẹ jẹ́ kí á lo àkàwé kan ninu ìrírí eniyan. Gẹ́gẹ́ bí àṣà, nígbà tí a bá ti ṣe majẹmu tán, kò sí ẹni tí ó lè yí i pada tabi tí ó lè fi gbolohun kan kún un.

Ka pipe ipin Galatia 3

Wo Galatia 3:15 ni o tọ