Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Galatia 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará Galatia, ẹ mà kúkú gọ̀ o! Ta ni ń dì yín rí? Ẹ̀yin tí a gbé Jesu Kristi tí wọ́n kàn mọ́ agbelebu sí níwájú gbangba!

Ka pipe ipin Galatia 3

Wo Galatia 3:1 ni o tọ