Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Filipi 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ohun tí ẹ ti kọ́ lọ́dọ̀ mi, tí ẹ bá lọ́wọ́ mi, tí ẹ ti gbọ́ lẹ́nu mi, tí ẹ ti rí ninu ìwà mi, àwọn ni kí ẹ máa ṣe. Ọlọrun alaafia yóo sì wà pẹlu yín.

Ka pipe ipin Filipi 4

Wo Filipi 4:9 ni o tọ