Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ mọ̀ pé ohun rere tí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín bá ṣe, olúwarẹ̀ ìbáà jẹ́ ẹrú tabi kí ó jẹ́ òmìnira, yóo rí èrè gbà lọ́dọ̀ Oluwa.

Ka pipe ipin Efesu 6

Wo Efesu 6:8 ni o tọ