Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 6:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa gbadura fún èmi gan-an alára, pé kí n lè mọ ohun tí ó yẹ kí n sọ nígbà tí n óo bá sọ̀rọ̀. Ati pé kí n lè fi ìgboyà sọ̀rọ̀ tí àwọn eniyan yóo fi mọ àṣírí ìyìn rere

Ka pipe ipin Efesu 6

Wo Efesu 6:19 ni o tọ