Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ dúró gbọningbọnin. Ẹ fi òtítọ́ ṣe ọ̀já ìgbànú yín. Ẹ fi òdodo bo àyà yín bí apata.

Ka pipe ipin Efesu 6

Wo Efesu 6:14 ni o tọ