Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 5:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkàwé yìí ba yín mu. Ẹnìkọ̀ọ̀kan yín níláti fẹ́ràn aya rẹ̀ bí òun tìkararẹ̀. Aya sì níláti bọ̀wọ̀ fún ọkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Efesu 5

Wo Efesu 5:33 ni o tọ