Nítorí èyí ni Ìwé Mímọ́ ṣe sọ pé,“Nígbà tí ó lọ sí òkè ọ̀run,ó kó àwọn ìgbèkùn lẹ́yìn,ó sì fi ẹ̀bùn fún àwọn eniyan.”