Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 4:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ fi èké ṣíṣe sílẹ̀. Kí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín máa bá ẹnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́, nítorí gbogbo wa jẹ́ ẹ̀yà ara kan náà.

Ka pipe ipin Efesu 4

Wo Efesu 4:25 ni o tọ