Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn àwọn yìí ti ṣókùnkùn, ó sì ti yàtọ̀ pupọ sí irú ìgbé-ayé tí Ọlọrun fẹ́. Nítorí òpè ni wọ́n, ọkàn wọn ti le.

Ka pipe ipin Efesu 4

Wo Efesu 4:18 ni o tọ