Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí, mò ń gbadura pé kí ọkàn yín má ṣe rẹ̀wẹ̀sì nítorí ìpọ́njú tí mò ń rí nítorí yín. Ohun ìṣògo ni èyí jẹ́ fun yín.

Ka pipe ipin Efesu 3

Wo Efesu 3:13 ni o tọ