Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 2:8-9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí oore-ọ̀fẹ́ ni a fi gbà yín là nípa igbagbọ. Kì í ṣe nítorí iṣẹ́, ẹ̀bùn Ọlọrun ni. Kì í ṣe ìtorí iṣẹ́ tí eniyan ṣe, kí ẹnikẹ́ni má baà máa gbéraga.

Ka pipe ipin Efesu 2

Wo Efesu 2:8-9 ni o tọ