Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ẹ wà ní ipò ẹni tí kò mọ Kristi. Ẹ jẹ́ àjèjì sí àwọn ọmọ-ìbílẹ̀ Israẹli. Àwọn majẹmu tí ó ní ìlérí Ọlọrun ninu sì tún ṣe àjèjì si yín. Ẹ wà ninu ayé láìní ìrètí ati láìní Ọlọrun.

Ka pipe ipin Efesu 2

Wo Efesu 2:12 ni o tọ