Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípasẹ̀ Kristi ni a ti ní ìdáǹdè nítorí ẹ̀jẹ̀ tí ó ta sílẹ̀. Nípasẹ̀ rẹ̀ ni a ti rí ìdáríjì gbà fún àwọn ìrékọjá wa, gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Efesu 1

Wo Efesu 1:7 ni o tọ