Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efesu 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń gbadura pé kí Ọlọrun, Baba Oluwa wa Jesu Kristi, Baba ológo, lè fun yín ní ẹ̀mí ọgbọ́n, kí ó sì jẹ́ kí ẹ ní ìmọ̀ tí ó kún nípa òun alára.

Ka pipe ipin Efesu 1

Wo Efesu 1:17 ni o tọ