Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanaya 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo wá mu yín pada wálé nígbà náà,nígbà tí mo bá ko yín jọ tán:n óo sọ yín di eniyan patakiati ẹni iyì láàrin gbogbo ayé,nígbà tí mo bá dá ire yín pada lójú yín,Èmi OLUWA ni mo wí bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Sefanaya 3

Wo Sefanaya 3:20 ni o tọ