Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanaya 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọrin sókè, kí ẹ sì hó;ẹ̀yin ọmọ Israẹli!Ẹ máa yọ̀ kí inú yín sì dùn gidigidi,ẹ̀yin ará Jerusalẹmu!

Ka pipe ipin Sefanaya 3

Wo Sefanaya 3:14 ni o tọ