Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanaya 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní: “Mo ti gbọ́ ọ̀rọ̀ àbùkù tí àwọn ará Moabu ń sọ ati bí àwọn ará Amoni tí ń fọ́nnu, bí wọn tí ń fi àwọn eniyan mi ṣe yẹ̀yẹ́, tí wọ́n sì ń lérí pé àwọn yóo gba ilẹ̀ wọn. Nítorí náà bí èmi, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli, ti wà láàyè,

Ka pipe ipin Sefanaya 2

Wo Sefanaya 2:8 ni o tọ