Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanaya 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni iṣẹ́ tí Ọlọrun rán Sefanaya, ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedalaya, ọmọ Amaraya, ọmọ Hesekaya ní àkókò ìjọba Josaya, ọmọ Amoni, ọba Juda.

Ka pipe ipin Sefanaya 1

Wo Sefanaya 1:1 ni o tọ