Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Kiṣi, baba Saulu sọnù. Kiṣi bá sọ fún Saulu ọmọ rẹ̀ pé, “Mú ọ̀kan ninu àwọn iranṣẹ lẹ́yìn, kí ẹ lọ wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà wá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 9

Wo Samuẹli Kinni 9:3 ni o tọ