Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 9:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli bá mú Saulu ati iranṣẹ rẹ̀ wọ inú gbọ̀ngàn ńlá lọ, ó fi wọ́n jókòó sí ààyè tí ó ṣe pataki jùlọ níbi tabili oúnjẹ tí wọ́n fi àwọn àlejò bí ọgbọ̀n jókòó sí.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 9

Wo Samuẹli Kinni 9:22 ni o tọ