Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí wọ́n sọnù láti ìjẹta, ẹ má da ara yín láàmú, wọ́n ti rí wọn. Ṣugbọn ta ni ẹni náà tí àwọn eniyan Israẹli ń fẹ́ tóbẹ́ẹ̀? Ṣebí ìwọ ati ìdílé baba rẹ ni.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 9

Wo Samuẹli Kinni 9:20 ni o tọ