Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, gbọ́ tiwọn, ṣugbọn kìlọ̀ fún wọn gidigidi, kí o sì ṣe àlàyé gbogbo ohun tí ọba náà yóo máa ṣe sí wọn fún wọn dáradára.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8

Wo Samuẹli Kinni 8:9 ni o tọ