Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n wí fún un pé, “Wò ó, àgbà ti dé sí ọ, àwọn ọmọ rẹ kò sì tẹ̀lé àpẹẹrẹ rere rẹ. Yan ẹnìkan, gẹ́gẹ́ bí ọba fún wa, tí yóo máa ṣe alákòóso wa bí àwọn orílẹ̀-èdè yòókù.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8

Wo Samuẹli Kinni 8:5 ni o tọ