Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 8:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fún Samuẹli pé, “Ṣe ohun tí wọ́n fẹ́, kí o sì yan ọba fún wọn.” Samuẹli bá sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí olukuluku pada lọ sí ìlú rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8

Wo Samuẹli Kinni 8:22 ni o tọ