Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe àlàyé fún wọn pé, “Bí ọba yín yóo ti máa ṣe yín nìyí: Yóo sọ àwọn ọmọkunrin yín di ọmọ ogun, àwọn kan ninu wọn yóo máa wa kẹ̀kẹ́ ogun, àwọn kan yóo wà ninu ẹgbẹ́ ọmọ ogun tí ń fi ẹsẹ̀ rìn, àwọn kan yóo máa gun ẹṣin níwájú kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 8

Wo Samuẹli Kinni 8:11 ni o tọ