Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 7:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Filistia gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli péjọ sí Misipa, àwọn ọba Filistini kó àwọn eniyan wọn jọ láti gbógun tì wọ́n. Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli gbọ́, ẹ̀rù bà wọ́n.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7

Wo Samuẹli Kinni 7:7 ni o tọ