Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 7:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Samuẹli ní kí wọ́n kó gbogbo eniyan Israẹli jọ sí Misipa, ó ní òun óo gbadura sí OLUWA fún wọn níbẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7

Wo Samuẹli Kinni 7:5 ni o tọ