Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ìgbà náà, Kiriati Jearimu ni wọ́n gbé àpótí OLUWA sí fún nǹkan bíi ogún ọdún, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli sì ń ké pe OLUWA fún ìrànlọ́wọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 7

Wo Samuẹli Kinni 7:2 ni o tọ