Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ẹ kan kẹ̀kẹ́ ẹrù tuntun kan, kí ẹ sì tọ́jú abo mààlúù meji tí ń fún ọmọ lọ́mú tí ẹnikẹ́ni kò sì so àjàgà mọ́ lọ́rùn rí, ẹ so kẹ̀kẹ́ ẹrù náà mọ́ wọn lọ́rùn, kí ẹ sì lé àwọn ọmọ wọn pada sílé.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 6

Wo Samuẹli Kinni 6:7 ni o tọ