Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 6:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará ìlú Beti Ṣemeṣi ní, “Ta ló lè dúró níwájú OLUWA Ọlọrun mímọ́ yìí? Ọ̀dọ̀ ta ni yóo fẹ́ lọ, tí yóo fi kúrò lọ́dọ̀ wa?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 6

Wo Samuẹli Kinni 6:20 ni o tọ