Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn ará ilẹ̀ náà pe àwọn babalóòṣà wọn ati àwọn adáhunṣe wọn jọ, wọ́n bi wọ́n pé, “Báwo ni kí á ti ṣe àpótí OLUWA? Bí a óo bá dá a pada sí ibi tí wọ́n ti gbé e wá, kí ni kí á fi ranṣẹ pẹlu rẹ̀?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 6

Wo Samuẹli Kinni 6:2 ni o tọ