Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Aṣidodu rí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀, wọ́n ní, “Ọlọrun Israẹli ni ó ń jẹ àwa ati Dagoni, oriṣa wa níyà. A kò lè jẹ́ kí àpótí Ọlọrun Israẹli yìí wà lọ́dọ̀ wa níhìn-ín mọ́ rárá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 5

Wo Samuẹli Kinni 5:7 ni o tọ