Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 4:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ṣe ọkàn yín gírí, ẹ̀yin ọmọ ogun Filistini! Ẹ ṣe bí akọni, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, a óo di ẹrú àwọn ará Heberu gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti jẹ́ ẹrú wa, nítorí náà, ẹ ṣe bí akọni, kí ẹ sì jà.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:9 ni o tọ