Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà dáhùn pé, “Israẹli sá níwájú àwọn ará Filistia. Wọ́n pa ọpọlọpọ ninu wa, wọ́n pa Hofini ati Finehasi, àwọn ọmọ rẹ mejeeji pẹlu. Wọ́n sì gbé àpótí Ọlọrun lọ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:17 ni o tọ