Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà, àwọn ará Filistia kó ara wọn jọ láti gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli, àwọn ọmọ Israẹli náà bá kó ogun jáde láti bá wọn jà. Àwọn ọmọ ogun Israẹli pàgọ́ sí Ebeneseri, àwọn ọmọ ogun Filistini sì pa tiwọn sí Afeki.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:1 ni o tọ