Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 31:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Filistia bá àwọn ọmọ Israẹli jagun ní orí òkè Giliboa. Ọpọlọpọ ninu àwọn ọmọ ogun Israẹli kú, àwọn yòókù sì sá. Saulu ati àwọn ọmọ rẹ̀ pàápàá sá lójú ogun.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 31

Wo Samuẹli Kinni 31:1 ni o tọ