Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 30:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Dafidi dáhùn pé, “Ẹ̀yin arakunrin mi, ẹ ẹ̀ gbọdọ̀ ṣe bẹ́ẹ̀, nítorí gbogbo ohun tí OLUWA fifún wa. Òun ni ó pa wá mọ́ tí ó sì fún wa ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọmọ ogun tí wọ́n dojú ìjà kọ wá.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:23 ni o tọ