Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 29:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, dìde ní òwúrọ̀, ìwọ ati àwọn iranṣẹ oluwa rẹ, tí wọ́n bá ọ wá, kí ẹ sì máa lọ ní kété tí ilẹ̀ bá ti mọ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 29

Wo Samuẹli Kinni 29:10 ni o tọ