Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 28:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà dáhùn pé, “Kí ló dé tí o fi ń dẹ tàkúté fún mi láti pa mí? O ṣá mọ ohun tí Saulu ọba ṣe, tí ó lé gbogbo àwọn abókùúsọ̀rọ̀ ati àwọn oṣó kúrò ní Israẹli.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:9 ni o tọ