Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 28:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́sẹ̀kan náà, Saulu ṣubú lulẹ̀ gbalaja, nítorí pé ohun ti Samuẹli sọ dẹ́rùbà á gidigidi, àárẹ̀ sì mú un nítorí pé, kò jẹun ní gbogbo ọ̀sán ati òru náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:20 ni o tọ