Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 27:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi sì sọ fún Akiṣi pé, “Bí mo bá rí ojurere rẹ, jọ̀wọ́ fún mi ní ààyè ní ọ̀kan ninu àwọn ìletò agbègbè yìí kí n máa gbé. Kí ló dé tí èmi iranṣẹ rẹ yóo máa gbé inú ìlú kan náà pẹlu rẹ?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 27

Wo Samuẹli Kinni 27:5 ni o tọ