Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 26:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá bèèrè lọ́wọ́ Ahimeleki, ará Hiti ati Abiṣai ọmọ Seruaya, arakunrin Joabu pé, “Ta ni yóo bá mi lọ sí ibùdó Saulu?”Abiṣai dáhùn pé, “N óo bá ọ lọ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 26

Wo Samuẹli Kinni 26:6 ni o tọ