Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 26:23 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA a máa san ẹ̀san rere fún àwọn tí wọ́n bá jẹ́ olóòótọ́ ati olódodo. Lónìí, OLUWA fi ọ́ lé mi lọ́wọ́, ṣugbọn mo kọ̀ láti ṣe ọ́ ní ibi, nítorí pé ẹni àmì òróró OLUWA ni ọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 26

Wo Samuẹli Kinni 26:23 ni o tọ