Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:43-44 BIBELI MIMỌ (BM)

43. Dafidi ti fẹ́ Ahinoamu ará Jesireeli, ó sì tún fẹ́ Abigaili pẹlu.

44. Ṣugbọn Saulu ti mú Mikali, ọmọ rẹ̀ tí ó jẹ́ iyawo Dafidi, ó ti fún Paliti ọmọ Laiṣi tí ó wá láti Galimu pé kí ó fi ṣe aya.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25