Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi gbọ́ pé Nabali ti kú, ó ní, “Ìyìn ni fún OLUWA tí ó gbẹ̀san lára Nabali nítorí àfojúdi tí ó ṣe sí mi. Ìyìn ni fún OLUWA tí ó sì fa èmi iranṣẹ rẹ̀ sẹ́yìn kúrò ninu ṣíṣe ibi. OLUWA ti jẹ Nabali níyà fún ìwà burúkú rẹ̀.”Dafidi bá ranṣẹ sí Abigaili pé òun fẹ́ fẹ́ ẹ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:39 ni o tọ