Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Abigaili pada dé ilé ó bá Nabali ninu àsè bí ọba. Inú rẹ̀ dùn nítorí pé ó ti mu ọtí ní àmupara. Abigaili kò sì sọ nǹkankan fún un títí di òwúrọ̀ ọjọ́ keji.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:36 ni o tọ