Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá sì ń gbèrò láti ṣe ọ́ ní ibi tabi láti pa ọ́, OLUWA yóo dáàbò bò ọ́ bí eniyan ti ń dáàbò bo ohun ìní olówó iyebíye. Ṣugbọn àwọn ọ̀tá rẹ ni a óo parun.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:29 ni o tọ